Home Posts tagged England
Yoruba

Aare Buhari sọ àsọyan pàtàkì lórí isẹ ìdàgbàsókè

Aare Muhammadu Buhari tí sọọ di mímọ fún olootu ìjọba ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì Boris Johnson àwọn iṣẹ́ ìdàgbàsókè tó ń wáyé nílèyi, pàtàkì jùlọ labala ètò ọrọ ajé àti àgbékalè ètò náà. Àwọn aṣáájú méjèèjì lo ṣepàdé pò níbi apejopo ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì pẹ̀lú ilẹ̀ Africa fodun 2020 èyí tó wáyé nilu London. Ààrẹ Buhari ṣàlàyé fún […]Continue Reading