-
Ijoba Ipinle Ekiti Fagile Eto Ile Ijosin Fodun Titun Nitori Arun COVID-19
Ijoba Ipinle Ekiti ti fagile eto isin apapo adura to saaba maa n waye lojo ise akoko ni gbogbo odoodun. Gege bi atejade t’Alakoso feto iroyin, Ogbeni Akin Omole fisita so wipe, igbese naa lo waye lati fi dena itankale kokoro arun corona nipinle naa. Ko sai tun soo di mimo pe, Gomina Ipinle Ekiti,…