Leyin oniruru isun siwaju, akanse eto igbanisise eyiti yoo to lowo gbigba awon eeyan ile yi ti ko nise lowo bi egebrun lona egberin odin die niye, ni yoo bere lola ode yi yika orilede Nigeria.
Alakoso for oise ati igbanisise nile yii, Ogbeni Festus Keyamo so eyi di mimo, lori itakun Twitter re.
O sope, Aare Muhammadu Buhari ti buwoolu igbinaya eto naa pelu alaye pe gbogbo ipinle lo gbodo tele ase naa leye osoka.
Gege bi Ogbeni Keyamo se wi, eto naa l’ofojusun gbigba awon omo orilede yi egberun kookan si ise, lati ijoba ibile edegberin odin die eyi to ye ko waye lojo kini osu kewa odun to koja amo tiwon sun siwaju.
Elizabeth Idogbe