Home Posts tagged New Delhi
Yoruba

Ilẹ̀ Nàijírìa àti Chad sọ̀rọ̀pọ̀ lórí isẹ́ àgbẹ̀

Orólẹ̀èdè wa Nàijírìa, ilẹ̀ olóminira Niger àti orílẹ̀èdè Chad ti ńsisẹ́ lórí àkànse ètò láti fi se àtúnse ibùdó adágún odò Chad, kí ètò ìgbáyégbádùn ba lè wà fáwọn èèyàn tó wà lágbègbè adágún odò na. Ọga àgbà àjọ kan tí wọ́n ń pè ní National Agency for the great green wall, ọ̀mọ̀wé Bukar Continue Reading