Home Posts tagged Olórí òsìsẹ́
News Yoruba

Olórí òsìsẹ́ sàmúlò àwọn ìlànà tí yo mu kísẹ́ múná dóko

Ìjọba àpapọ̀ ti fagilé sísàmúlò ìwé àbọ̀ láti mọ bí òsìsẹ́ ọba seń sisẹ́ sí lọ́dọdún èyí tí wọ́n ń dape lédè gẹ́ẹ̀si ni Annual Performance Evaluation Report Aper. Olórí òsìsẹ́ nílẹ̀ yí Ọmọwe Fọlasade Yẹmi Ẹsan ló jẹ́ kọ́rọ̀ yí di mímọ̀ nílu Continue Reading