Home Posts tagged Abdulrasheed Akanbi
Yoruba

Oluwo korò ojú sí buba ajínigbé sètùtù tí wọ́n rí ní Ìwó

Olúwo ti Ìwóm ọba Abdulrasheed Akanbi ti fi àidùnú rẹ̀ hàn lórí bí wọ́n ti se àwárí bùba ajínigbé sètùtù ní agbègbè rẹ̀. Ọba Akanbi nínú àtẹ̀jáde tó fi síta ni ó jẹ́ ohuntí ó yani lẹ́nu pé àwọn ènìyàn ìlú Ìwó sì léè pani sètùtù lẹ́yìn gbogbo ìpolongo rẹ̀ lórí dídẹ́kun irú ìwà ibi […]Continue Reading