Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọyọ ti kéde ìpinu rẹ̀ láti ta àwọn ilégbe méjìdínlógójì tówà ní “Calton-Gate Estate” Àkóbọ̀ ìbàdàn fáwọn arálu lówó tí o gajura lọ. Alákoso fọ́rọ̀ ilẹ̀ ilégbe àti ìdàgbàsókè ẹsẹ̀kùkú, ọ̀gbẹ́ni Abiọdun Abdu-Raheem ló jẹ́ kọ́rọ̀ yi di mímọ̀ lásìkò tón se àbẹ̀wò sáwọn ilégbe tó Continue Reading