-
Egbe òsèlú PDP sọ ìrètí rè nípa Àmọ̀tẹ́kùn
Oludamọ̀ràn pàtàkì lórí ètò gbogbo àti on tonise pẹ̀lú òsèlú fún Gómìnà Seyi Makinde tipínlè Ọ̀yọ́, Ogbeni Babatunde Oduyoye sọ pé ìwé tí wọ́n ní Alakoso lóri ọ̀rọ̀ ètò idajọ nílè yíì Abubakar Malami ko lórí ọ̀rọ̀ ìjọba ìbílè ńipinle Ọ̀yọ́ ni kò yẹ kọ́kọ́, nítorípé ọ̀rọ̀ náà ti wà nílé ẹjọ́. Nínú atejade èyí…