Oludamọ̀ràn pàtàkì lórí ètò gbogbo àti on tonise pẹ̀lú òsèlú fún Gómìnà Seyi Makinde tipínlè Ọ̀yọ́, Ogbeni Babatunde Oduyoye sọ pé ìwé tí wọ́n ní Alakoso lóri ọ̀rọ̀ ètò idajọ nílè yíì Abubakar Malami ko lórí ọ̀rọ̀ ìjọba ìbílè ńipinle Ọ̀yọ́ ni kò yẹ kọ́kọ́, nítorípé ọ̀rọ̀ náà ti wà nílé ẹjọ́.

Nínú atejade èyí tí Ógbéni Oduyoye fisita sọ pé niwon gba ti ọ̀rọ̀ ohùn ti wà níwájú ilé ẹjọ́ ìrètí wa pé kò yẹ kí enikeni tún gbé ìgbéṣe lórí rè mọ lábé òfin.

Ó ṣàlàyé síwájú pé, ìwé tí wọ́n ní ó jáde láti ofisi adajo àgbà nílè yíì Abubakar Malami ló sese kó dá ìkùnsínú sílè ńipinle yi. 

Atejade náà wá ro gbogbo àwọn tọrọ náà kàn nìdí ètò ìjọba láti kiyesara lórí on tí wọ́n yọ má sọ notoripe ọ̀rọ̀ ohùn wa níwájú ilé ẹjọ́. 

Kẹmi Ogunkọla/Iyabọ Adebisi

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *