Home Posts tagged Àhájì Mohammed Bello
Yoruba

Ọga àgbà ilésẹ́ Radio Nigeria ẹkùn ìbàdàn bèrè fún gbígbé ìròyìn tí yóò fẹsẹ ìsòkan múlẹ̀

Olùdarí àgbà ilésẹ́ Radio Nigeria ìbàdàn, tó fẹ́ fẹ̀yìntì, Àhájì Mohammed Bello, ńfẹ́ káwọn oníròyìn máà wádi ohun gbogbo kí wọ́n sì ridájú pé, ìròyìn tó fìdí múlẹ̀ nìkan ni wọn ńgbé síta fún ìsọ̀kan ilẹ̀ yíì. Àlhájì Bello ẹnitó sọ̀rọ̀ yíì lásìkò tó ńkopa lórí ètò ilésẹ́ Premier F.M lédè gẹssi Continue Reading