Home Posts tagged Àjọ Ẹ̀sọ́ Ojú Pópó
News Yoruba

Àjọ Ẹ̀sọ́ Ojú Pópó Tẹnumọ́ Pàtàkì Àsẹ Sísàmúlò Ẹ̀rọ Asòdinwọ̀n Eré Sísá

Àjọ ẹ̀sọ́ ojú pópó nílẹ̀ Náigírìa ti sọpé dandan ni fífi sára ọkọ̀ ohun sísàmúlò ẹ̀rọ asòdinwọ̀n eré sísá fáwọn awakọ̀ kólè mú àdínkùn bá eré àsápajúdé lójú pópó. Ọga àgbà àjọ náà fún ìpínlẹ̀ Ògùn, ọ̀gbẹ́ni Ahmed umar ló yọjú ọ̀rọ̀ náà síta lásìkò ìfọ̀rọ̀wérọ̀ pẹ̀lú àwọn akọ̀ròyìn nílu Ọta. Continue Reading
Yoruba

Àjọ Ẹ̀sọ́ Ojú Pópó Gbé Ìgbésẹ̀ Láti Fòpinsí Súnkẹrẹ Fàkẹrẹ Ọkọ̀

Àjọ ẹ̀sọ́ ojú pópó, nílẹ̀ yíì, FRSC ẹ̀ka tìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti gùnlé ìparáarọ tí wọn pè orúkọ rẹ̀ ní operation Zero’’ láti fi kojú súnkẹrẹ fàkẹrẹ ọkọ̀ láwọn òpópónà ńlá ńlá. Ọga àgbà àjọ náà nípinlẹ̀ yí, Arábìnrin Uche Chukwurah ní ìgbésẹ̀ náà se pàtàkì láti léè jẹ́kí èróngbà wọn láti máse sàkọsílẹ̀ ìjànbá ọkọ̀ […]Continue Reading