Home Posts tagged Ajọ MPB
News Yoruba

Ajọ MPB Tako Ọ̀rọ̀ Àyẹ̀wò Ìwé Ẹ̀rí

Àjọ tó ńrísí ọ̀rọ̀ àwọn ajagun fẹ̀yìntì nílẹ̀ yíì, MPB, sọpé irọ́ tó jína sóòtọ láhesọ ọ̀rọ̀ tó ńjà ràiràn pé àjọ náà yóò bẹ̀rẹ̀ àyẹ̀wò ìwé ẹ̀rífáwọn ọmọ ẹgbẹ́ látọ jọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n osù kọkànlá sí ọjọ́ kẹsan osù kejìlá. Èyí jẹyọ nínú àtẹ̀jáde tálukoro àjọ MPB, ọ̀gágun Ọlayinka Lawal fisíta Continue Reading