Home Posts tagged Àjọ NSCDC
Yoruba

Àjọ NSCDC àti àwọn tọ́rọkàn bèèrè fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ lórí àmójútó ìjàmbá

   Àwọn tọ́rọkàn nídi bíbójútó ìsẹ̀lẹ̀ ìjàmbá ti pè fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ àwọn ará ìlú nídi ríri pé wọ́n tètè dìde ìrànwọ́ lásìkò tí ìjàmbá bá wáyé lágbègbè wọn. Wọ́n fìpè yí síta níbi ìdánilẹ́kọ ọlọ́gọ́ méjì lórí bíbójútó ìsẹ̀lẹ̀ ìjàmbà èyítí àjọ àabò ara ẹni làabò ìlú, NCDC, ẹ̀ka tìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ Continue Reading