Home Posts tagged Àlhájì Musa Sarkiadar
Yoruba

Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Àpapọ̀ Kejì Ti Ń Tanná Wo Àbá Ìsúná Àjọ NNPC Lorí Ẹbu Ìfọpo

Pẹ̀lú bí ìjọba àpapọ̀ seń fikun iye jálá epo àti àwọn èròjà tó rọ̀ mọ, ilé ìgbìmọ̀ asòfin ńfẹ́ kí wọ́n wá sọ bí wọ́n ti náà owó tó lé ní billiọnu mẹ́fàlélọ́gọ́ta naira tó wà nínú àbá ìsúná fún síse isẹ́ àkànse àtúnse àjọ tón mójútó epo rọ̀ọ̀bì NNPC, nínú àbá ìsúná ọdún 2021. […]Continue Reading