Mẹ́ta nínú àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ alásẹ ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ni àyẹ̀wò ti fihàn wípé wọ́n ti ní àrún covid-19. Alága ìgbìmọ̀ amúsẹ́yá lórí covid-19 nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, Gómìnà Seyi Makinde ló sísọ lójú ọ̀rọ̀ yí lórí ìkànnì abẹ́yẹfò rẹ̀. Ó sàlàyé wípé ìjọba gba èsì àyẹ̀wò gbogbo àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ alásẹ ìpínlẹ̀ Continue Reading