Home Posts tagged Bàbá kérésì
Yoruba

Bàbá kérésì ilésẹ́ Premier FM àti Amuludun FM yóò gunlẹ̀ lọ́la òde yíì

Bàbá kérésì ilésẹ́ Premier F.M 93.5 àti taúludùn F.M 99.1 yóò gunlẹ̀ bàagẹ̀ lọ́la òde yíì. Àtẹ̀jáde kan, èyítí ìgbìmọ̀ ètò náà fisíta sọpé, àwọn ẹ̀bùn jàkàn-jàkàn ni yóò wà fáwọn òge wẹrẹ yíì lárin ago mẹ́wa òwúrọ̀ ságo márun ìrọ̀lẹ́ pẹ̀lú ẹgbẹ̀rún kan náirà péré. Àtẹ̀jáde ọ̀hún sèlérí pé, Continue Reading