-
Ijoba Apapo Gbe Igbese Pinpin Owo Lati Madinku Ba Ipa Aarun COVID-19
Ijoba apapo pelu ajosepo banky agbaye, yoo pin egberindinlaadota million dollar ni ipinle merindinlogoji to w anile yi, lati madinku ba ipa aarun covid-19. Alakoso keji feto isunaa ati aato gbogbo, Ogbeni Clem Agba so eyi nilu Abuja. O salaye pe, ipinle kokan yoo gba ogun million dollar, nigba tii million medoogun dollar yo je…
-
Banki Agbaye se atileyin fun ipinle eko lori ise akanse kiko opopona to wo awon oko
Ijoba ipinle Eko ti so pee to iranwo eyi ti banki Agbaye gbe kale lati mu kagbega deba akowo ati igbaye gbadun araalu, ni yo se atileyin fun ise akanse kilo opopona to wo oko to le ni ibuso agbegbe oko merin otooto. Alakoso feto ogbin nipinle Eko, Arabinrin Abisola Olusanya, lo je koro yi…
-
Ijoba Apapo Sope Kosi Otoo Oro Ninu Abo Iroyin Banki Agbaye Pe Ina – Oba Ojaa Faafaa Lorilede Yii
Ijoba apapo sope iro tojina soo too nii abo iwadi banki agbaye tonii, ida mejidinlogorin awon onibara ilesa ina oba lorilede yii ni ki ni ina –oba fun wakati mejila loojo. Olubadamoran Pataki saare foro igbayegbadun , ogbeni ahmad zakari enito soro yii nilu Abuja, sope koye won liana isiro ti banki agbaye lo lori…
-
Banki Agbaye Nawo Iranwo Si Eka Ina Oba Lorile Ede Naijiria
Banki agbaye ti buwolu owoya oni millionu eedegberin o le ni aadota, 750 million dollars ti egbe to wa fun idagbasoke lagbaye fun agbedide eka ina oba nile Naijiria. Ninu atejade ti banki naa fi sita nilu Abuja, o ni igbese naa ni won gbe lati lee ri pe eka ina oba tubo fese rinle…