Home Posts tagged CNN Expose
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ bu ẹnu àtẹlu àbọ̀ ìròyìn ilésẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ CNN lórí ìsẹ̀lẹ̀ ìbọn yínyìn ládugbò Lẹ́kkí

Alákoso fọ́rọ̀ ìròyìn àti àsàà, Lai Mohammed ti sọ̀rọ̀ lórí àbọ̀ ìwádi lórí ìbọn yínyìn tó wáyé lógúnjọ́ osù kẹwa lágbègbè Lẹ́kkí, èyí tí ilésẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ nílẹ̀ America CNN, gbé síta. Ọgbẹni Mohammed sàpèjúwe àbọ̀ ọ̀hún gẹ́gẹ́bí èyí tó fíì sojukan , tí kò sì sọ bí ọ̀rọ̀ ti rí gan, bákanà Continue Reading