Home Posts tagged Dr Ọlọrunnibẹ Mamora
Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Ńkọminú L’órí B’áwọn Tóní Àisàn Ọ̀rẹ̀rẹ̀ Se Ń Pọ̀si

Ìjọba àpapọ̀ tin kọminú bí iye àwọn tóní àisàn iba ọ̀rẹ̀rẹ̀ seń pọ̀si láwọn ìpínlẹ̀ kọ̀kan. Alákoso fétò ìlera, Dókítà Ọlọrunnibẹ Mamora ló fìdí ọ̀rọ̀ yí múlẹ̀ nílu Abuja pẹ̀lú àtọ́katí pé pẹ̀lú bí àsìkò ẹ̀rùn se ń wọlé dé, wọ́n ti ń fi ìdí ìsẹ̀lẹ̀ àisàn náà múlẹ̀ láwọn ìpínlẹ̀ kọ̀kan nílẹ̀ yí. Continue Reading