Home Posts tagged Ẹgbẹ́ àwọn Gómìnà
Yoruba

Ẹgbẹ́ àwọn Gómìnà ńfẹ́ kíjọba àpapọ̀ se àtúntò ohun àmúsọrọ̀ fáwọn ìpínlẹ̀

Alága ẹgbẹ́ àwọn Gómìnà nílẹ̀ yíì, ọ̀mọ̀wé Kayọde Fayẹmi ti pè fún àtúntò ohun àmúsọrọ̀ láarin àwọn ẹ̀ka ìjọba gbogbo nítorí ìdàgbàsókè ilẹ̀ yí lápapọ̀. Ó pèpè yí níbi ètò àpérò ọlọ́dọdún ẹlẹẹkẹta iruẹ, tó fi mọ́ ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọdún kọkànléláadọrin lẹ́yìn ìpapodà, èyí tó wáyé fún Gómìnà àná Continue Reading