Home Posts tagged ètò ilégbe
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ mú àtúnse bá ètò ilégbe fáwọn èèyàn tí kò rọ́wọ́ họrí

Ètò àgbékalẹ̀ ilégbe tó jẹ́ ọ̀kan gbogi nídi fífẹsẹ̀ èróngbà ìdúrósinsin ètò ọrọ̀ ajé ilẹ̀ yíì múlẹ̀, làfojúsùn rẹ̀ jẹ́ ìgbésẹ̀ ìrọ̀rùn fáwọn èèyàn tówó tó ń wọlé fún wọn, kó tó ùnkan. Olùrànlọ́wọ́ pàtàkì fáarẹ Muhammadu Buhari lórí ọ̀rọ̀ ìgbáyégbádù, arábìnrin Imeh Okoh tó fìdí èyí múlẹ̀ nílu Continue Reading