Home Posts tagged Fòpinsí Súnkẹrẹ Fàkẹrẹ Ọkọ̀
Yoruba

Àjọ Ẹ̀sọ́ Ojú Pópó Gbé Ìgbésẹ̀ Láti Fòpinsí Súnkẹrẹ Fàkẹrẹ Ọkọ̀

Àjọ ẹ̀sọ́ ojú pópó, nílẹ̀ yíì, FRSC ẹ̀ka tìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti gùnlé ìparáarọ tí wọn pè orúkọ rẹ̀ ní operation Zero’’ láti fi kojú súnkẹrẹ fàkẹrẹ ọkọ̀ láwọn òpópónà ńlá ńlá. Ọga àgbà àjọ náà nípinlẹ̀ yí, Arábìnrin Uche Chukwurah ní ìgbésẹ̀ náà se pàtàkì láti léè jẹ́kí èróngbà wọn láti máse Continue Reading