Home Posts tagged hand Washing
Yoruba

Alákoso fọnrere àsà ọwọ́ fífọ̀

Alákoso fọ́rọ̀ ohun àlùmọ́nì inú omi, onímọ̀ẹ̀rọ Suleiman Adamu, ló ń fẹ́ káwọn ọmọdé kásà bééyan se fọwọ́ lóre kóre pẹ̀lú ọsẹ àtomi, látidpenà ọ̀kan ọ̀jọ̀kan àrùn. Omímọ̀ẹ̀rọ Adamu tó sàlàyé pé pàtàkì ọwọ̀ fífọ̀, rọ àwọn alágbàtọ́ láti kásà ìmọ́tótó fi dábòbò àwọn ọmọdé kúrò lọ́wọ́ àwọn àrùn Continue Reading