Yoruba

Alákoso fọnrere àsà ọwọ́ fífọ̀

Alákoso fọ́rọ̀ ohun àlùmọ́nì inú omi, onímọ̀ẹ̀rọ Suleiman Adamu, ló ń fẹ́ káwọn ọmọdé kásà bééyan se fọwọ́ lóre kóre pẹ̀lú ọsẹ àtomi, látidpenà ọ̀kan ọ̀jọ̀kan àrùn.

Omímọ̀ẹ̀rọ Adamu tó sàlàyé pé pàtàkì ọwọ̀ fífọ̀, rọ àwọn alágbàtọ́ láti kásà ìmọ́tótó fi dábòbò àwọn ọmọdé kúrò lọ́wọ́ àwọn àrùn lọ́lọ́kan òjọ̀kan.

Kò sài sọ́ọ́di mímọ̀ pe, ìjọba kòní káarẹ láti pèsè omi tómọ́ gaara, èyí tí yóò wà lárọwọ́tó gbogbo aráalu, láti dènà àwọn àisàn tó ń tara omi jáde.

Kò sài fikun pé, ọwọ́ pẹ̀lú se pàtàkì tó sì máà ń kópa tó jọjú lórí ìmọ́tòtò ara, óúnjẹ àtàwọn ǹkan min-in tóda bi rẹ̀.

Kẹmi Ogunkọla/Seyifunmi Ọlarinde

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *