Ibùdóìgbafẹ́ ìjọba àpapọ̀ tó wà nílu Ọyọ, ni wọ́n ti fi àmìn ẹ̀yẹ dá àwọn òsìsẹ́ tó sẹ̀sẹ̀ gba àgbéga lẹ́nu isẹ́ lọ́lá èyí tó yàtọ̀ gédégbé sí báwọn òsìsẹ́ kan séngba ìwé àgbéga tẹ́lẹ̀rí tí wọ́n yo sì fipamọ́. Akọ̀ròrìn ilésẹ́ Radio Nigeria fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pe, ìgbésẹ̀ tuntun yi lówà níbamu pẹ̀lú Continue Reading