-
Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ yio gbàlejò ìdíje ẹ̀sẹ́ kíkàn àgbáyé
Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ni yio gbàlejò ìdíje ẹ̀sẹ́ kínkàn àgbáyé ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n osù yí. Alága ìgbìmọ̀ tó ńse kòkárí ìdíje náà Ọlawale Okuniyi ló sísọ lójú ọ̀rọ̀ yí lásìkò tó kó ikọ̀ ìgbìmọ̀ rẹ̀ sòdí wá gbé bẹ́lìtì ìdíje náà wá han Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde lọ́fìsì rẹ̀ tó wà l’Ajodi nílu…