Home Posts tagged iléesẹ́ ọlọ́pa ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́
Yoruba

Iléesẹ́ Ọlọ́pa Kìlọ̀ Fáràalú Láti Kóra Wọn Níjanu Lásìkò Ọdún

Alákoso iléesẹ́ ọlọ́pa ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, ọ̀gbẹ́ni Nwachukwu Enwonwu ti sèkìlọ̀ fáwọn aráàlu pé kí wọ́n yàgò fún lílo òfin lọ́wọ́ ará wọn, léyi tó dàpè ní ìdájọ́ láàye ara ẹni. Alákoso sípaya ọ̀rọ̀ yí nílu ìbàdàn pẹ̀lú àlàyé wí pé, káwọn èèyàn tètè máà fi ọ̀rọ̀ tó iléésẹ́ ọlọ́pa tó bá wà nítòsí Continue Reading