-
Awon eekan nilese aare, setan fun abere ajesara
Aare Muhammadu Buhari, igbakeji Aare, Ojogbon Yemi Osinbajo atawon eekan nile yii, ti setan lati waa lara awon ipe akoko awon eeyan ile yi ti yoo tha abere ajesara covid-19. Oludari ajo apapo to nrisi idagbasoke eto ilera, NPHCDA, Dokital Faisal Shuaib soro yi nilu Abuja nibi abo ise iko amuseya ijoba apapo farun covid-19.…