Ilese olopa nipinle oyo, ti bere igbese fifofinde lilo oko yafun yafun , siren, lona aito, lilo awon number idanimo oko ti won boo, lilo oko to ayee awako wa lowo otun tofimo oko ti eto ifonikosile re oti waye. Eyi jeyo ninu atejade kan, eyiti agbenuso ilse olopa nipinle oyo, ogbeni olawale Continue Reading
Ọkùnrin kan Joseph Johnson ẹni ọdún mẹ́tàlélógún ni ónkáwọ́pọ̀n sẹ́yìn níwájú ilé ẹjọ́ magisrate nípinlẹ̀ Ọsun, nílu Osogbo, láti sàlàyé on tórí labẹ̀ tó fi garu ọwọ́, lórí kíkùnà láti gba ìwé ìrìnà sílẹ̀ Canada fún oníbarà rẹ̀. Arákùnrin yi, ni ìròyìn fìdí ẹ̀ múlẹ̀ pe ó gba ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹdẹgbẹrin naira lọ́wọ́ Bukọla Alayande, […]Continue Reading