Home Posts tagged Independent National Electoral Commission (INEC)
Yoruba

Àjọ INEC Fẹ́ Sàmúlò Ọ̀nà Ìgbàlódé Ètò Ìdìbò

Àjọ elétò ìdìbò ilẹ̀ yíì INEC, ní òun ti sàgbékalẹ̀ ọ̀nà ìgbàlódé nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ láti fòpin sí màgòmágó ìbò àti wípé wọ́n ti ńsisẹpọ pẹ̀lú àwọn àjọ elétò ààbò, àjọ tó ńrísí ìwà àjẹbánu àti èyítí ó ńgbógunti oogun olóró NDLEA, láti fojú ẹnikẹ́ni tó bá lọ́wọ́ nínú rira ìbò àti jíjí àpóótí ìbò Continue Reading