Tag: Kaadi Idanimo

  • Kaadi Idanimo: Sisayewo Oye Awon Olugbe Igberiko Atesekuku

    Kaadi Idanimo: Sisayewo Oye Awon Olugbe Igberiko Atesekuku

    Oniruru igbese lo dabi pe ijoba ngbe bayi lati gbogun tiwa odaran lawujo, okan ninu re si nipe kawon eeyan ni kaadi idanimo torilede yi lowo. Iwadi fihan pe latigba tijoba ti kede gbedeke asiko tawon eeyan gbodo se eleyi lawon budo tiwon ti nse eleyi ti beresi kun akunfaya. Nje awon olugbe igberiko atesekuku…