Home Posts tagged Margret Chan
Yoruba

Orílẹ̀ èdè Nàijírìa ti kúrò láwùjọ àwọn tí wọ́n ní àrùn rọmọlápá rọmọ lẹ́sẹ̀ – W.H.O

Àjọ elétò ìlera lágbyé W.H.O ti kéde pé, ilẹ̀ Nàijírìa rọmọlápárọmọlẹ́sẹ́ ti jàjàbọ́ kúrò lọ́wọ́ àrù polio. Àjọ náà lórí òpó ẹ̀rọ abẹ́yẹfò rẹ̀, iyin twitter sọ pé ní lọ́lọ́ yí orílẹ̀ èdè méjì péré ni àrùn polio bá ńfira, èyí ló sì ti mú kó jẹ́ pé gbogbo àgbáyé ló ti fẹ́ fòpin s;i […]Continue Reading