Home Posts tagged Mr Geoffrey Onyeama
Yoruba

Alákoso Tẹ́lẹ̀ Fétò Ìsúná, Ngozi Okonjo Iweala Fọọkàn Àwọn Èèyàn Ilẹ̀ Yí Balẹ̀ Lórí Ìpèsè Abẹ́rẹ́ Àjẹsára Covid-19

Alákoso tẹ́lẹ̀ fétò ìsúná, ọ̀mọ̀wé Ngozi Okonjo iweala ti fọwọ́ sọ̀yà fàwọn èèyàn ilẹ̀ yíì àtàwọn orílẹ̀èdè ilẹ̀ Africa tókù lóórí ìpèsè abẹ́rẹ́ àjẹsára fárùn covid-19, láti ìparí osù kini ọdún tónbọ̀. Ó sọ̀rọ̀ yíì lẹ́yìn ìpàdé alátìlẹ̀kùmọ́rí se pẹ̀lú alákoso fọ́rọ̀ ilẹ̀ òkòrè, ọ̀gbẹ́ni Geoffrey Onyeama nílu Abuja. Ọmọwe Okonjọ Iweala, tise asojú àjọ […]Continue Reading