-
Ìdúnadúrà láarin ìjọba àti ẹgbẹ́ òsìsẹ́ ńtẹ̀síwájú
Ìdúnadúrà tó ń wáyé láarin ìjọba àpapọ̀ àtẹgbẹ́ òsìsẹ́ lórí ọ̀rọ̀ owó osù àwọn òsìsẹ́ tókéré jùlọtún bẹ̀rẹ̀ lóni nílu Abuja. Ìpàdé náà tí wọn ò forí rẹ̀ tìsíbìkan lána niwọ́n tún gùnlé ní dédé ago méjì ọ̀sán òní. Igbákejì àarẹ ẹgbẹ́ òsìsẹ́ nílẹ̀ yíì, ọ̀gbẹ́ni Amaechi Asugunim, fi ìrètí hàn pe, ìpàdé náà yóò…