Home Posts tagged Ogbeni Boss Mustapha
Yoruba

Ìjọba Kéde Ìlànà Ìkánilọ́wọ́kò Tuntun Lórí Àrùn COVID-19

Àarẹ Muhammadu Buhari ti pàsẹ kí wọ́n ti àwọn ilé otí, àwọn ilé ijó àti àwọn ibùdó ayẹyẹ tó fi mọ́ àwọn ibùdó ìgbafẹ́ fún ọ̀sẹ̀ márun láti léè dènà ìtànkálẹ̀ àrùn COVID-19. Ó tún pàsẹ kí wọ́n ti àwọn ilé óunjẹ ìgbàlódé nígbàtí àwọn ilé ìwé yio wà ni títì títí di ọjọ́ kejìdínlógún […]Continue Reading