Home Posts tagged Ọ̀gbẹ́ni Wasiu Ẹshinlokun-Sanni
Yoruba

Ilé Ìgbìmọ̀ Asòfin Nípinlẹ̀ Èkó Gbé Ìgbésẹ̀ Láti Sètò Ìrànwọ́ Fáwọn Tó Fara Kásá Lásìkò Ìfẹ̀húnúhàn #EndSARS

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin nípinlẹ̀ Èkó ti lọ rí lára àwọn tí wọ́n fura pé, wọ́n fara kásá lásìkò ìfẹ̀húnúhàn Endsars láti lè mọ pàtó ètò ìrànwọ́n tí wọ́n yo se fún wọn. Igbákejì adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin, Ọ̀gbẹ́ni Wasiu Ẹshinlokun-Sanni, ló jẹ́ kọ́rọ̀ yí di mímọ̀, lásìkò ìjọko ilé ọlọ́jọ́ mẹ́ta pàtàkì Continue Reading