Home Posts tagged ọ̀gbìn ìgbàlódé
News Yoruba

Àarẹ Muhammadu Buhari pè fún lílọ́wọ́ àwọn ọ̀dọ́ sẹ́ka ètò ọ̀gbìn ìgbàlódé.

Àarẹ orílẹ̀dè yíì Muhammadu Buhari ti ké sáwọn àjọ tọ́rọkàn lẹ́ka ètò ọ̀gbìn láti lọ́wọ́ àwọn ọ̀dọ́ sáwọn ìlànà ètò ọ̀gbìn ìgbàlódé lẹ́ka náà.  Ìlú Abuja láarẹ ti sísọ lójú ọ̀rọ̀ yíì lákokò tón sèfilọ́lẹ̀ ètò kan tóníse pẹ̀láwọn àgbẹ̀ òde ìwòyí, èyí tẹ́ka tónrísí ìdàgbásókè ilẹ̀ ọ̀gbìn Continue Reading