-
Onímọ̀ gbàmọ̀ràn lórí èròjà tó lè dípò epo bẹtirolu
Ọjọgbọn kan nínú ìmọ̀ sísàwárí epo rọ̀ọ̀bì àti ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ìwakùsà, Olugbenga Ehinola ti késí ìjọba àpapọ̀ pe kó náwó sí ọ̀rọ̀ ìpèsè èròjà tó wọn ń pè ni Hydrocarbon èyí tí wọ́n lè ma lò dípò epo rọ̀ọ̀bì, tó sì jẹ́ pé inú àpáta ni wọ́n ti ń ríì. Ọjọgbọn Ehinola sọ̀rọ̀ yí nígbà…