-
Gómìnà Masari tẹ́wọ́gba àwọn ọmọ iléwe Kankara, tó gba ìyọ̀nda
Àwọn ọmọkùnrin ọmọ ilé ìwé ìmọ̀ Sciensi tó wà ní Kankara tó lé ní ọọdunrun tí wọ́n jí gbé lọ, tí wọ́n gba òmìnira lálẹ́ àná ni wọ́n ti gúnlẹ̀ si ìpínlẹ̀ Kastina báyi. Àwọn akẹ́kọ náà ni àwọn òsìsẹ́ aláabo sìn wọ olú ìlú ìpínlẹ̀ náà. Diẹ lára wọn ni wọ́n si wọ asọ…