Home Posts tagged Ọsinbajo
News Yoruba

Igbákejì àarẹ Ọsinbajo tẹnumọ́ ìdí tó fi yẹ káràlú nígbọkànlé nínú ìjọba.

Ìjọba àpapọ̀ sọ pé, ó ti pa dandan báyi láti fẹsẹ̀ ìgbọkànlé múlẹ̀ daindain láàrin ìjọba àti arálu, lẹ́yìn ìfẹ̀húnúhàn fífi òpin sí ẹ̀ka Sars. Igbákejì àrẹ, ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Ọinbajo ló sọ̀rọ̀ yí lásìkò àkànse ètò láti se àtúnse on Continue Reading