-
Àwọn Ilé Epo Kò Tẹ̀lé Àsẹ Láti Mádinkù Bá Owó Epo
Àwọn ilé epo nílu ìbàdàn ni wọ́n ò tẹ̀lé àsẹ láti mú àdínkù bá owó tí wọ́n ńta jálá bẹntirol sí naira méjìlélọ́gọ́jọ gẹ́gẹ́bí ìjọba àpapọ̀ tise pàsẹ rẹ̀ lọ́sẹ̀ tó kọjá. Akọ̀ròyìn ilé isẹ́ Radio Nigeria tó sàbẹ̀wò sáwọn ilé epo kan lágbègbè Apẹtẹ, Mọ́kọ́lá, Sángo àti Dùgbẹ̀ sàkíyèsi pé naira méjìdínláadọsan ni wọn…