Home Posts tagged Political Class Salary
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ ńgbèrò àtúngbéyẹ̀wò owó àwọn tó dipò òsèlú mú

Ìjọba àpapọ̀ ti sọ pé, kòní pẹ́ tó n yóò fi sàgbéyẹ̀wò owó osù gbogbo àwọn tó dipò òsèlú mú pátá. Ìlú Abuja lalákoso fọ́rọ̀ isẹ́ àti ìgbanisísẹ́, ọ̀mọ̀wé Chris Ngige ti sísọ lójú ọ̀rọ̀ yíì, lákokò àbẹ̀wò ẹgbẹ́ àwọn òsìsẹ́ láwọn ìjọba ìbílẹ̀. Gẹ́gẹ́ bó se wípé, ó sepàtàkì kíwọ́n sàgbéyẹ̀wò owó Continue Reading