Home Posts tagged Resort Centre nílu ìbàdàn
Yoruba

Ìpínlẹ̀ Ọyọ sètò àpérò lórí owóna àti ìgbanisísẹ́

Àwọn asòfin ní ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ Ọyọ ńsètò ìpàdé ọlọ́jọ́ mẹ́rin lọ́wọ́ báyi lórí àbá òfin mẹ́ta kan tó sepàtàkì. Àwọn àbá òfin ọ̀hún ni, àbà tóníse pẹ̀lú àgbéga àjọ tó ń dá isẹ́ ajé sílẹ̀ ọdún 2019, àbá tí níse pẹ̀lú àjọ tó ńgbóguntí ìwà àbàjẹ́ tófimọ́ àbá tóníse pẹ̀lú àtúntò àti ìdúró Continue Reading