-
Ile Asofin Gba Ijoba Nimoran Lori Sisi Ileewe Pada N’ipinle Oyo
Ile Igbimo Asofin Ipinle Oyo ti gba Igbimo alase nimoran pe ki won wo bi oju ojo se ri nipa ajakale arun Covid-19 ki won to si awon ile-iwe pada gege bi won se ngbero re. Eyi lo waye nipa bi oro naa se nile igbese kiakia wipe aba ti omo ile Asofin naa ti…