Adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ Ọyọ, ọ̀gbẹ́ni Debọ Ogundoyin ti gba alága àtàwọn ìgbìmọ̀ tẹkótó ilé ẹlẹ́ni márùndínlọ́gbọ̀n níyànjú láti sisẹ́ wọn bí isẹ́. Adarí ilé gbé àmọ̀ràn yíì kall lákokò tó ńbura fún ìgbìmọ̀ náà níbi ètò kan èyí tí pínpín ìwé òfin àtẹ̀lée fáwọn ìgbìmọ̀ ọ̀hún tí wáyé Continue Reading