Home Posts tagged Àrẹ Buhari
Yoruba

Àrẹ Buhari tẹnumọ́ ríri dájú pé orílẹ̀ èdè Nàijírìa wà ní ìsọ̀kan

Àrẹ Muhammadu Buhari sọpé ìsèjọba rẹ̀ yo tẹ̀síwájú nínú síse isẹ́ to kí ilẹ̀ Nàijírìa wà ní ìsọ̀kan, kétò ọrọ̀ ajé rẹ̀ si tún dúró digbí tó sì tún jẹ́jẹ láti gbéná wojú àwọn tón domi àlàfìa ìlú rú. Àrẹ Buhari sọ̀rọ̀ yí lásìkò tón gba àwọn asojú ìgbìmọ̀ àgbàgbà láti ìpínlẹ̀ Borno àti Yobe […]Continue Reading
Yoruba

Àrẹ Buhari ńfẹ́ àmúlò fífi òdiwọ̀n si lílò àwọn on ìjagun nílẹ̀ adúláwọ̀.

Àrẹ Muhammadu Buhari ti rọ àwọn asájú nílẹ̀ adúláwọ̀ láti mú àgbéga bá sísàmúlò, mímú òdinwọ̀n bá lílò ìjagun olóró, kí ìsọ̀kan àti àláfìa le débá ètò àbò láwùjọ lápapọ̀. Àrẹ Buhari sọ̀rọ̀ yí lásìkò ìpàdé pàtàkì ẹlẹkẹrinla, ilẹ adúláwọ̀ ni mímú àgbéga bá àláfìa, ètò àbò, ìsọ̀kan, àti mímúkí rògbòdìyàn dópin nílẹ̀ adúlọ́wọ̀, pẹ̀lú […]Continue Reading