Home Posts tagged Babatunde Fashola
Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Ńgbèrò Láti Mú Píparí Isẹ́ Àkànse Lọ́kunkúndùn

Ìjọba àpapọ̀ sọ pé òun yo tẹpẹlẹ píparí àwọn isẹ́ àkànse ojú òpópónà àti afárá tón lọ lọ́wọ́ nílẹ̀ Nìajírìa dípò bíbẹ̀rẹ̀ isẹ́ àkànse tuntun, nínú sísàmúlò àbá ìsúná fún tọdún 2021. Alákoso fọ́rọ̀ isẹ́ àti ilégbe, ọ̀gbẹ́ni Babatunde Fashọla tó sọ̀rọ̀ yí nílu Abuja, tọ́kasi pé, irúfẹ́ àwọn isẹ́ àkànse òpópónà tójẹ́ méjìdínlógún níye, […]Continue Reading