Home Posts tagged Minister Of Industry
Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Ti Tẹnumọ́ Ìpinu Rẹ̀ Láti Sàmúlò Ètò Tí Yo Mú Kétò Ọrọ Ajé Rú Gọ́gọ́si

Ìjọba àpapọ̀ ti pèsè owó tó lé ní billiọnu méjìlá naira fáwọn ilé-isẹ́ olókowò kékèké àti talábọ́dé, n’ípasẹ̀ àwọn ilé ìfowófamọ́ olókowò, gẹ́gẹ́ bí ara akitiyan láti pinwọ́ ìpalára ti ìbẹ́sílẹ̀ àrùn covid-19 sokùnfà rẹ̀. Alákoso ilé-isẹ́ okòwò àti ìdásẹ́alé sílẹ̀, ọ̀gbẹ́ni Niyi Adebayọ tó sọ̀rọ̀ yíì di mímọ̀ níbi àpérò kan tó wáyé nílu […]Continue Reading