Home Posts tagged Nigeria Airforce
Yoruba

Ilé isẹ́ ọmọológun òfurúfú pàdánù obìnrin àkọ́kọ́ tó ńwa báàlù ìjagun

Ilésẹ́ ọmọ ológun òfurúfú sọpé àwọn ti pàdánù, obìrin àkọ́kọ́ tó ńwa ọkọ̀ báàlù ìjagun ọ̀gágun Tolulọpẹ Arotile, nínú ìjàmbá ọkọ̀ kan tówáyé nílu Kaduna. Ọga àgbà lẹ́ka ìròyìn nílesẹ́ ọ̀hún, ọ̀gágun Ibikunle Daramọla, kéede ìpapòdà ọ̀gágun Arotile nínú àtẹ̀jáde kan nílu Abuja. Ológbe ọ̀hún ló gba àgbéga lọ́dún tókọjá, látọwọ́ ọ̀gágun àgbà Saddique Abubakara […]Continue Reading