Home Posts tagged Professor Bolanle Olaniyan
Yoruba

Wọ́n Ti Ké Sáwọn Obìnrin Láti Máà, Sàyẹ̀wò Ọyàn Wọn Lórekóòre

Aya igbákejì Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, Bọlanle Ọlaniyan tún ti tẹnumọ ìdí tó fi sepàtàkì káwọn èèyàn máà lọ fáyẹ̀wò ọyàn wọn, kíwọ́n lè ba tètè tọ́jú èyíkèyí ohun tí wan bá kẹ́fín níbẹ̀, kó tó pẹ́jù. Ọjọgbọn Ọlaniyan tó fìdí èyí múlẹ̀ níbi ètò ìpolongo kan, lọfisi aya Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ pẹ̀lú Continue Reading